Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Iya Yoruba láti Èrèlé , 2019
#FreeAmade: Akọ̀ròyìn tí a mú tí a sì dá lóró lẹ́yìn tí ó kọ ìròyìn lórí ìwà jàgídí jàgan tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní Àríwá Mozambique
Àwọn ọlọ́pàá Mozambique ju akọ̀ròyìn náà sí àhámọ̀ níbi tí ó ti ń jábọ̀ ìròyìn ní Cabo Delgado
Ilé-iṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Ìbílẹ̀ Fagilé Ìfọ̀rọ̀wọ́rọ̀ pẹ̀lú àwọn ajìjàǹgbara LGBT lẹ́yìn ìhalẹ̀mọ́ sí olóòtú
Èébú ìkórìíra-ìbálòpọ̀-láàárín-akọ-àti-akọ ní orí ayélujára kò ṣí ọkàn-an olóòtú kúrò, àmọ́ ìpè ẹni àjèjì ń dá ẹ̀ru ìwà ìkà bá àwọn àlejòo rẹ̀.