Àṣẹ̀sẹ̀tẹ̀jáde ìròyìn látọwọ́ọ Abdulrosheed Fádípẹ̀
Ìdí tí àwọn ilé-Iṣẹ́ ònímọ̀ ẹ̀rọ tó làmìlaaka fi gbọdọ̀ múra sí akitiyan wọn lórí Ìṣafikún àwọn èdè Ilẹ̀ Adúláwọ̀
Nǹkan bíi 523 nínú àwọn èdè 3000 tí wọ́n ń kú lọ tí yóò sì kú àkúrun nígbà tí yóò bá fi di ìparí ọ̀rúndún kọkànlélógún ní àwọn ènìyàn ń sọ ní orílẹ̀ Afíríkà.