Ìròyìn láti Ẹrẹ́nà , 2021
Rising Voices’ Activismo Lenguas gba Àmì-ẹ̀yẹ Èdè Abínibí Àgbáyé
"Àmì-ẹ̀yẹ yìí dúró gẹ́gẹ́ bí ipa tí àwọn ajìjàngbara èdè lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ń ní jákèjádò agbègbè Latin Amẹ́ríkà àti arapa ribiribi iṣẹ́ wọn."
O rí gbogbo èdè òkè wọ̀nyẹn? A ṣe ìtumọ̀ ìròyìn Global Voices (Ohun Àgbáyé) láti mú ìròyìn ará ìlú àgbáyé sétígbọ̀ọ́ ènìyàn gbogbo.
"Àmì-ẹ̀yẹ yìí dúró gẹ́gẹ́ bí ipa tí àwọn ajìjàngbara èdè lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ń ní jákèjádò agbègbè Latin Amẹ́ríkà àti arapa ribiribi iṣẹ́ wọn."