Èbìbì , 2020

Ìròyìn láti Èbìbì , 2020

Túwíìtì nípa èdè Ilẹ̀-Adúláwọ̀ àti ẹ̀tọ́ sí ìlò ẹ̀rọ ayárabíàṣá

Ohùn Tó-ń-dìde

Rising Voices ń kọ́mọlùbọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ẹ wa ní yàrá ìròyìn Ohùn Àgbáyé Agbègbè Sahara Ilẹ̀-Adúláwọ̀ fún ìpolongo tuntun lórí ẹ̀rọ alátagbà láti ṣe àyẹ̀wò ìbáṣepọ̀ tí ó ń bẹ láàárín àwọn èdè Ilẹ̀-Adúláwọ̀ àti ẹ̀tọ́ sí ẹ̀rọ ayárabíàṣá.

4 Èbìbì 2020