Ẹrẹ́nà , 2019

Ìròyìn láti Ẹrẹ́nà , 2019

Twitter @DigiAfricanLang 2019

Ohùn Tó-ń-dìde  19 Ẹrẹ́nà 2019

Tweets by @DigiAfricanLang Bẹ̀rẹ̀ láti ogúnjọ́ oṣù Ẹrẹ́nà títí di òpin ọdún-un 2019, àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá á máa ṣe ‘ọ̀ọ̀wẹ̀’ láti ṣàkóso aṣàmúlò Túwítà @DigiAfricanLang ní tẹ̀lé-ǹ-tẹ̀lé, aṣàmúlò tuntun náà á máa ṣàfihàn ipa tí ìmọ̀-ẹ̀rọ ń kó nínú ìgbélárugẹ àti ìgbéǹde àwọn èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀....