Ìròyìn láti 11 Ṣẹẹrẹ 2023
Àjọ tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn ní Turkey ní àwọn obìnrin ò le dá nìkan rin ìrìn-àjò
Ìgbà àkọ́kọ́ tí àjọ ẹ̀sìn ní ìlú Turkey yóò lépa àwọn obìnrin àti òmìnira wọn kọ́ lèyìí, tí ó sì tún ń yẹpẹrẹ wọ́n láwùjọ.
Bí ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Atlas Lions ti Morocco ṣe fi ìtàn balẹ̀ nínú ìdíje ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé 2022
Ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Morocco, Atlas Lions ni ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù àkọ́kọ̀ ní ilẹ̀ Áfríkà àti ilẹ̀ Lárúbáwá tí yóò kọ́kọ́ dé ìpele tí ó kángun sí ìparí nínú ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé.