Ìlàkàkà láti fi òpin sí òkúrorò SARS ẹ̀ka ilé-isẹ́ ọlọ́pàá ilẹ̀ Nàìjííríà ń tẹ̀síwájú.
Ìbéèrè lórí ẹni tí ó ń darí àwọn Ọlọ́pàá àti ikọ̀ SARS kò tíì fi gbogbo ara rí ìdáhùn. Ìwé-òfin ilẹ̀ náà gbágbára ìdárí lé ààrẹ
lọ́wọ́, ó sì gbé agbára àmójútó lé Ọ̀gá àgbà ilé iṣẹ́ Ọlọ́pàá lọ́wọ́.
Copy and paste this URL into your WordPress site to embed
Copy and paste this code into your site to embed